Home

An iconic of educations

and motivation

+ Spiritualisim

of Yorubaland

radio station,

                     

Yaagbo yaaju oke Tiiri mawo

Https BALOGUN RADIO

Balogun radio ikanni radio Yoruba pelu asa ise isedale toun Toro aje Yoruba ati igbelaruge Ede Yoruba Nile loko ati leyin odi papajulo fun ikonilede Awon omo wa loke okun kamaba gbagbe ati ma shamulo asa wa ni igba gbogbo .

Gbedu Oro extra
ni eto tao ti ma parawa lerin
tao si ma yan nannan agbara tin be ninu ipinu eda

BALOGUN RADIO

Akin niwaju ogun Awon pedepede

Ajegbayi

Ajegbayi

eto Tao ti ma yannanan

didasile oja Nile wa

ati iforo wani lenu wo bi

Oro aje senlo

lorile Ede wa

pelu agbaye

Balogun radio

                             Odetode

Eto pelu Olalekan Akinwale,

eto taati maa se

iforo wani lenu, wo

pelu Awon ogboju, ode,

Nipa eranko ati iriri won,

Nipa ise ode .

Every Saturday
Ode to ode 730 pm to 8 pm
west African time

Balogun Radio

is a radio station

that celebrates the rich

and diverse culture

of the Yoruba people.

Our mission

is to promote

Yoruba language,

economy, music,

and traditions

to a global audience.

We play a variety

of Yoruba music,

from traditional drumming

to contemporary pop,

showcasing the rich

musical heritage

of the Yoruba people.

Our programming

also includes

informative shows

on Yoruba culture,

history, and language,

as well as news and current

events from across the

Yoruba-speaking region.

Balogun Radio

is among the best

radio to celebrate

and promote the rich

and vibrant heritage,

music and tradition of

the Yoruba people.

@olukolo

Meet the man
Adetolani Aremu Awurela
director Balogun Radio

Balogun Televission

Tap the icon

AKOKO OLUFE TINRO KOOROKO

Social media links

Tap to check

Design a site like this with WordPress.com
Get started